Music: Oluwafiolakemi – Baba Faanu Gbami

0

Another amazing song from the outstanding gospel music minister “Olúwafiolákémi” a.k.a. (Àgbéké Oní Sèkèrè Oba), as she comes again with an awesome song titled “Baba F’àánú Gb’àmí”. This is a prayer-base song, and is sure to bless your heart and launch you to God’s realm of blessings. Be blessed with God’s unstoppable mercy as you download, listen and share.

Download Mp3

“BABA F’ÀÁNÚ GB’ÀMÍ” SONG LYRICS

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o,
Jésú f’àánú gb’àmí o,
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o,
Àánú re l’ayé mí n’ílò (x2)

Verse:
Aráyé nwò mí mó o l’ára..
Aráyé npè mí mó o Jésù..
Wòólì Jésù tún ti nlo…
Omo Olórun àbò re a dà..
K’ómo aláso mi má wàkísà oo
K’ómo eléran mi má j’asán oo
Ááà Agbani l’ágbàtán m’odé ooo dákun!
F’àánú re gbémi dìde..

Call:
Baba f’ánu gb’àmì

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o, (Omo Olórun mo sá di o)
Jésú f’àánú gb’àmí o, (ení gb’ójú lé o, k’òní j’ogún òfo)
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o, (Àsìkò mi titó Babá)
Àánú re l’ayé mí n’ílò (Ìwo ló gb’omo Ébérù n’ínú iná)

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o, (O f’owó agbára re f’agi kédarì ya, pátá-pátá)
Jésú f’àánú gb’àmí o, (Àlágbawí gbàmí o baba)
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o, (f’anú gb’àmí x3)
Àánú re l’ayé mí n’ílò (x2)

Bridge:
L’órí òkè yí f’anú gb’àmí o..
Eni tó le sé f’anú gba’yé mi..
B’ómo kìnìhún bá n s’aláìní ò eee
Ti wón sì nkígbe ebi kíkan-kíkan..
Èmí s’átiní Olùgbàlà…
Èmi k’òní s’aláìní ohun tó dára…
Atóbijù yára bòwá ooo dákun, F’àánú re gbémi dìde

Call: Baba f’anú gb’àmí..

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o, (Abiyamo b’òjá gbòòrò-gbooro m’odé)
Jésú f’àánú gb’àmí o, (nkò l’élòmíràn l’éyìn re ò baba mi)
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o, (ení gb’ójú lé o k’òní j’ogún òfo láé-láé)
Àánú re l’ayé mí n’ílò (F’àánú re y’ígbà wa padà sí rere)

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o, (k’amá s’egbé erú, k’amá s’ákó bàtà f’égbé láé-láé)
Jésú f’àánú gb’àmí o, (orí lè èdè yí d’owó re ò Baba)
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o, (F’àánú re y’ígbà wa padà sí rere)
Àánú re l’ayé mí n’ílò (Olórun àgbáyé tiwá d’owó re)

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o, (Baba mímó f’anú re gbàwá)
Jésú f’àánú gb’àmí o, (ka máse r’ítàjè s’ílè mo ò láé-láé baba)
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o, (je k’ódodo re kó b’orí ní gbogbo ònà pátá-pátá-pátá)
Àánú re l’ayé mí n’ílò (ááà Baba d’ákun gb’àwá)

Chorus:
Baba f’àánú gb’àmí o, (mo gb’ójú mi s’ókè sí Olorun mi)
Jésú f’àánú gb’àmí o, (ní ibi tí ìrànlówó mi yíò wa ti wá Bábá)
Èmí mímó f’àánú gb’àmí o, (ìrànlówó mi yíò t’owó Elédùmarè wa)
Àánú re l’ayé mí n’ílò (nítorípé, àánú re l’ayé mí n’ílò)

END!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *